20Nígbà tó yá, gbogbo àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní Dánì+ títí lọ dé Bíá-ṣébà àti ilẹ̀ Gílíádì,+ gbogbo àpéjọ náà sì kóra jọ sójú kan* níwájú Jèhófà ní Mísípà.+
22 Ọba Ásà wá pe gbogbo Júdà, láìyọ ẹnì kankan sílẹ̀, wọ́n kó àwọn òkúta àti ẹ̀là gẹdú tó wà ní Rámà, tí Bááṣà fi ń kọ́lé, Ọba Ásà sì fi wọ́n kọ́* Gébà+ ní Bẹ́ńjámínì àti Mísípà.+