2 Kíróníkà 12:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ní ti ìtàn Rèhóbóámù, láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ wòlíì Ṣemáyà+ àti ti Ídò+ aríran tó wà nínú ìtàn ìdílé? Ìgbà gbogbo ni ogun ń wáyé láàárín Rèhóbóámù àti Jèróbóámù.+
15 Ní ti ìtàn Rèhóbóámù, láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ọ̀rọ̀ wòlíì Ṣemáyà+ àti ti Ídò+ aríran tó wà nínú ìtàn ìdílé? Ìgbà gbogbo ni ogun ń wáyé láàárín Rèhóbóámù àti Jèróbóámù.+