1 Àwọn Ọba 2:44 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 44 Lẹ́yìn náà, ọba sọ fún Ṣíméì pé: “Nínú ọkàn rẹ, o mọ gbogbo jàǹbá tí o ṣe fún Dáfídì bàbá mi,+ Jèhófà yóò sì dá jàǹbá náà pa dà sórí rẹ.+ 1 Àwọn Ọba 2:46 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 46 Ni ọba bá pàṣẹ fún Bẹnáyà ọmọ Jèhóádà, Bẹnáyà jáde lọ, ó ṣá a balẹ̀, ó sì kú.+ Bí ìjọba náà ṣe fìdí múlẹ̀ gbọn-in lọ́wọ́ Sólómọ́nì nìyẹn.+
44 Lẹ́yìn náà, ọba sọ fún Ṣíméì pé: “Nínú ọkàn rẹ, o mọ gbogbo jàǹbá tí o ṣe fún Dáfídì bàbá mi,+ Jèhófà yóò sì dá jàǹbá náà pa dà sórí rẹ.+
46 Ni ọba bá pàṣẹ fún Bẹnáyà ọmọ Jèhóádà, Bẹnáyà jáde lọ, ó ṣá a balẹ̀, ó sì kú.+ Bí ìjọba náà ṣe fìdí múlẹ̀ gbọn-in lọ́wọ́ Sólómọ́nì nìyẹn.+