-
1 Àwọn Ọba 19:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ó wọnú ihò+ kan níbẹ̀, ó sì sùn mọ́jú; sì wò ó! Jèhófà bá a sọ̀rọ̀, ó sọ fún un pé: “Kí lò ń ṣe níbí, Èlíjà?” 10 Ó fèsì pé: “Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun+ gbà mí lọ́kàn ni; nítorí àwọn èèyàn Ísírẹ́lì ti pa májẹ̀mú rẹ tì,+ wọ́n ti ya àwọn pẹpẹ rẹ lulẹ̀, wọ́n ti fi idà pa àwọn wòlíì rẹ,+ èmi nìkan ló sì ṣẹ́ kù. Ní báyìí, bí wọ́n ṣe máa gba ẹ̀mí* mi ni wọ́n ń wá.”+
-