Ẹ́kísódù 3:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mósè ń bójú tó agbo ẹran Jẹ́tírò+ bàbá ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà Mídíánì. Nígbà tó ń da agbo ẹran náà lọ sí apá ìwọ̀ oòrùn aginjù, ó dé Hórébù, òkè Ọlọ́run tòótọ́.+ Ẹ́kísódù 19:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Èéfín ń rú ní gbogbo Òkè Sínáì, torí Jèhófà sọ̀ kalẹ̀ sórí rẹ̀ nínú iná;+ èéfín rẹ̀ sì ń lọ sókè bíi ti iná ìléru, gbogbo òkè náà sì ń mì tìtì.+ Málákì 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Ẹ rántí Òfin Mósè ìránṣẹ́ mi, àwọn ìlànà àti àṣẹ tí mo pa fún gbogbo Ísírẹ́lì ní Hórébù pé kí wọ́n tẹ̀ lé.+
3 Mósè ń bójú tó agbo ẹran Jẹ́tírò+ bàbá ìyàwó rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà Mídíánì. Nígbà tó ń da agbo ẹran náà lọ sí apá ìwọ̀ oòrùn aginjù, ó dé Hórébù, òkè Ọlọ́run tòótọ́.+
18 Èéfín ń rú ní gbogbo Òkè Sínáì, torí Jèhófà sọ̀ kalẹ̀ sórí rẹ̀ nínú iná;+ èéfín rẹ̀ sì ń lọ sókè bíi ti iná ìléru, gbogbo òkè náà sì ń mì tìtì.+
4 “Ẹ rántí Òfin Mósè ìránṣẹ́ mi, àwọn ìlànà àti àṣẹ tí mo pa fún gbogbo Ísírẹ́lì ní Hórébù pé kí wọ́n tẹ̀ lé.+