Sáàmù 50:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọlọ́run wa yóò wá, kò sì ní dákẹ́.+ Iná tó ń jó nǹkan run wà níwájú rẹ̀,+Ìjì tó lágbára sì ń jà ní gbogbo àyíká rẹ̀.+ Àìsáyà 29:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa fún ọ láfiyèsíPẹ̀lú ààrá, ìmìtìtì ilẹ̀ àti ariwo ńlá,Pẹ̀lú ìjì, atẹ́gùn líle àti ọwọ́ iná tó ń jẹni run.”+
3 Ọlọ́run wa yóò wá, kò sì ní dákẹ́.+ Iná tó ń jó nǹkan run wà níwájú rẹ̀,+Ìjì tó lágbára sì ń jà ní gbogbo àyíká rẹ̀.+
6 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa fún ọ láfiyèsíPẹ̀lú ààrá, ìmìtìtì ilẹ̀ àti ariwo ńlá,Pẹ̀lú ìjì, atẹ́gùn líle àti ọwọ́ iná tó ń jẹni run.”+