-
Jeremáyà 50:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Jèhófà ti ṣí ilé ìṣúra rẹ̀,
Ó sì ń mú àwọn ohun ìjà ìbínú rẹ̀ jáde.+
Nítorí Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, ní iṣẹ́ kan
Ní ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà.
-
-
Náhúmù 1:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Ọ̀nà rẹ̀ wà nínú ẹ̀fúùfù àti ìjì líle,
Àwọsánmà sì ni eruku ẹsẹ̀ rẹ̀.+
-