2 Sámúẹ́lì 8:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Jóábù+ ọmọ Seruáyà ni olórí àwọn ọmọ ogun, Jèhóṣáfátì+ ọmọ Áhílúdù sì ni akọ̀wé ìrántí.