ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 31:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 Tí mo bá mú wọn dé ilẹ̀ tí mo búra nípa rẹ̀ fún àwọn baba ńlá wọn,+ ilẹ̀ tí wàrà àti oyin ti ń ṣàn,+ tí wọ́n jẹun tẹ́rùn, tí nǹkan sì ń lọ dáadáa fún wọn,*+ wọ́n á lọ máa tọ àwọn ọlọ́run míì lẹ́yìn, wọ́n á sì máa sìn wọ́n, wọ́n á hùwà àfojúdi sí mi, wọ́n á sì da májẹ̀mú mi.+

  • Sáàmù 78:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Ọkàn wọn ò ṣe déédéé pẹ̀lú rẹ̀;+

      Wọn ò sì pa májẹ̀mú rẹ̀ mọ́.+

  • Àìsáyà 1:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 O gbé! Ìwọ orílẹ̀-èdè ẹlẹ́ṣẹ̀,+

      Àwọn èèyàn tí ẹ̀ṣẹ̀ wọ̀ lọ́rùn,

      Ìran àwọn èèyàn burúkú, àwọn ọmọ oníwà ìbàjẹ́!

      Wọ́n ti fi Jèhófà sílẹ̀;+

      Wọ́n ti hùwà àfojúdi sí Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì;

      Wọ́n ti kẹ̀yìn sí i.

  • Jeremáyà 22:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Wọ́n á fèsì pé: “Torí pé wọ́n fi májẹ̀mú Jèhófà Ọlọ́run wọn sílẹ̀, wọ́n forí balẹ̀ fún àwọn ọlọ́run míì, wọ́n sì ń sìn wọ́n.”’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́