-
Ẹ́kísódù 14:18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Ó dájú pé àwọn ará Íjíbítì yóò mọ̀ pé èmi ni Jèhófà nígbà tí mo bá tipasẹ̀ Fáráò, àwọn kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ àti àwọn agẹṣin rẹ̀ ṣe ara mi lógo.”+
-
-
Sáàmù 37:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àmọ́ àwọn ẹni burúkú yóò ṣègbé;+
Àwọn ọ̀tá Jèhófà yóò pòórá bí ibi ìjẹko tó léwé dáadáa;
Wọ́n á pòórá bí èéfín.
-