1 Àwọn Ọba 20:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Àmọ́ wòlíì kan wá bá Áhábù+ ọba Ísírẹ́lì, ó sọ fún un pé: “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Ṣé o rí gbogbo èèyàn rẹpẹtẹ yìí? Màá fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́ lónìí, wàá sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’”+
13 Àmọ́ wòlíì kan wá bá Áhábù+ ọba Ísírẹ́lì, ó sọ fún un pé: “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Ṣé o rí gbogbo èèyàn rẹpẹtẹ yìí? Màá fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́ lónìí, wàá sì mọ̀ pé èmi ni Jèhófà.’”+