ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 1:51, 52
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 51 Wọ́n wá ròyìn fún Sólómọ́nì pé: “Wò ó, ẹ̀rù Ọba Sólómọ́nì ti ń ba Ádóníjà; ó sì ti lọ gbá àwọn ìwo pẹpẹ mú, ó sọ pé, ‘Kí Ọba Sólómọ́nì kọ́kọ́ búra fún mi pé òun ò ní fi idà pa ìránṣẹ́ rẹ̀.’” 52 Ni Sólómọ́nì bá sọ pé: “Tí kò bá kọjá àyè rẹ̀, kò sí ìkankan nínú irun orí rẹ̀ tó máa bọ́ sílẹ̀; àmọ́ tí a bá rí ohun tí kò dára lọ́wọ́ rẹ̀,+ ó gbọ́dọ̀ kú.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́