- 
	                        
            
            1 Àwọn Ọba 22:31Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        31 Ọba Síríà ti pàṣẹ fún àwọn méjìlélọ́gbọ̀n (32) tó jẹ́ olórí kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀ pé:+ “Ẹ má ṣe bá ẹnikẹ́ni jà, ì báà jẹ́ ẹni kékeré tàbí ẹni ńlá, àfi ọba Ísírẹ́lì.” 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            1 Àwọn Ọba 22:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        35 Ìjà náà le gan-an jálẹ̀ ọjọ́ yẹn, kódà wọ́n ní láti gbé ọba nàró nínú kẹ̀kẹ́ ẹṣin bí wọ́n ṣe ń bá àwọn ará Síríà jà. Ẹ̀jẹ̀ ọgbẹ́ náà ń dà jáde sínú kẹ̀kẹ́ ogun náà, ó sì kú ní ìrọ̀lẹ́.+ 
 
-