-
2 Kíróníkà 18:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Nítorí náà, ó sọ pé: “Mo rí i tí gbogbo ọmọ Ísírẹ́lì tú ká lórí àwọn òkè, bí àwọn àgùntàn tí kò ní olùṣọ́.+ Jèhófà sọ pé: ‘Àwọn yìí kò ní ọ̀gá. Kí kálukú pa dà sí ilé rẹ̀ ní àlàáfíà.’”
-