-
Nọ́ńbà 36:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Ogún èyíkéyìí tó jẹ́ ti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kò gbọ́dọ̀ ti ọwọ́ ẹ̀yà kan bọ́ sí òmíràn, torí kò yẹ kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì fi ogún ẹ̀yà baba ńlá wọn sílẹ̀.
-