Émọ́sì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nítorí mo mọ bí ìdìtẹ̀* yín ṣe pọ̀ tóÀti bí ẹ̀ṣẹ̀ yín ṣe pọ̀ tóẸ̀ ń dààmú àwọn olódodo,Ẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀,*Ẹ sì ń fi ẹ̀tọ́ àwọn aláìní dù wọ́n ní ẹnubodè.+ Hábákúkù 1:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Òfin kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ mọ́,Kò sì sí ìdájọ́ òdodo rárá. Torí àwọn ẹni ibi yí olódodo ká;Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń yí ìdájọ́ po.+
12 Nítorí mo mọ bí ìdìtẹ̀* yín ṣe pọ̀ tóÀti bí ẹ̀ṣẹ̀ yín ṣe pọ̀ tóẸ̀ ń dààmú àwọn olódodo,Ẹ̀ ń gba àbẹ̀tẹ́lẹ̀,*Ẹ sì ń fi ẹ̀tọ́ àwọn aláìní dù wọ́n ní ẹnubodè.+
4 Òfin kò lẹ́sẹ̀ nílẹ̀ mọ́,Kò sì sí ìdájọ́ òdodo rárá. Torí àwọn ẹni ibi yí olódodo ká;Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń yí ìdájọ́ po.+