ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóòbù 12:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Àgọ́ àwọn olè wà ní àlàáfíà,+

      Àwọn tó sì ń mú Ọlọ́run bínú wà láìséwu,+

      Àwọn tí ọlọ́run wọn wà ní ọwọ́ wọn.

  • Sáàmù 12:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Àwọn ẹni burúkú ń rìn káàkiri fàlàlà

      Nítorí pé àwọn ọmọ èèyàn ń gbé ìwà ìbàjẹ́ lárugẹ.+

  • Oníwàásù 8:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Nítorí pé a kò tètè mú ìdájọ́ ṣẹ lórí ìwà burúkú,+ ọkàn àwọn èèyàn le gbagidi láti ṣe búburú.+

  • Àìsáyà 1:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ẹ wo bí ìlú olóòótọ́+ ṣe di aṣẹ́wó!+

      Ìdájọ́ òdodo kún inú rẹ̀ tẹ́lẹ̀;+

      Òdodo ń gbé inú rẹ̀ nígbà kan,+

      Àmọ́ ní báyìí, àwọn apààyàn ló wà níbẹ̀.+

  • Ìṣe 7:52, 53
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 52 Èwo nínú àwọn wòlíì ni àwọn baba ńlá yín kò ṣe inúnibíni sí?+ Bẹ́ẹ̀ ni, wọ́n pa àwọn tó kéde pé olódodo náà ń bọ̀,+ ẹni tí ẹ dalẹ̀ rẹ̀ tí ẹ sì pa,+ 53 ẹ̀yin tí ẹ gba Òfin bí ó ṣe wá látọ̀dọ̀ àwọn áńgẹ́lì+ àmọ́ tí ẹ kò pa á mọ́.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́