28 Mósè wá sọ pé: “Èyí á jẹ́ kí ẹ mọ̀ pé Jèhófà ló rán mi ní gbogbo ohun tí mò ń ṣe yìí, kì í ṣe ohun tó kàn wù mí: 29 Tó bá jẹ́ pé bí gbogbo èèyàn ṣe ń kú làwọn èèyàn yìí máa kú, tó bá sì jẹ́ irú ìyà ẹ̀ṣẹ̀ tí gbogbo aráyé ń jẹ làwọn náà máa jẹ, a jẹ́ pé Jèhófà kọ́ ló rán mi.+