1 Àwọn Ọba 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ọba ní ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun Táṣíṣì+ lórí òkun pẹ̀lú ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun ti Hírámù. Ẹ̀ẹ̀kan lọ́dún mẹ́ta ni ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun Táṣíṣì máa ń kó wúrà àti fàdákà, eyín erin,+ àwọn ìnàkí àti àwọn ẹyẹ ọ̀kín wọlé. Ìsíkíẹ́lì 27:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àwọn ará Dédánì+ bá ọ dòwò pọ̀; o gba àwọn oníṣòwò síṣẹ́ ní ọ̀pọ̀ erékùṣù; eyín erin+ àti igi ẹ́bónì ni wọ́n fi san ìṣákọ́lẹ̀* fún ọ.
22 Ọba ní ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun Táṣíṣì+ lórí òkun pẹ̀lú ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun ti Hírámù. Ẹ̀ẹ̀kan lọ́dún mẹ́ta ni ọ̀wọ́ ọkọ̀ òkun Táṣíṣì máa ń kó wúrà àti fàdákà, eyín erin,+ àwọn ìnàkí àti àwọn ẹyẹ ọ̀kín wọlé.
15 Àwọn ará Dédánì+ bá ọ dòwò pọ̀; o gba àwọn oníṣòwò síṣẹ́ ní ọ̀pọ̀ erékùṣù; eyín erin+ àti igi ẹ́bónì ni wọ́n fi san ìṣákọ́lẹ̀* fún ọ.