-
2 Kíróníkà 20:35-37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Lẹ́yìn náà, Jèhóṣáfátì ọba Júdà bá Ahasáyà ọba Ísírẹ́lì da nǹkan pọ̀, ẹni tó ń hùwà burúkú.+ 36 Nítorí náà, ó fi í ṣe alábàáṣiṣẹ́ láti máa ṣe àwọn ọkọ̀ òkun tí á máa lọ sí Táṣíṣì,+ wọ́n sì ṣe àwọn ọkọ̀ òkun náà ní Esioni-gébérì. + 37 Àmọ́, Élíésérì ọmọ Dódáfáhù láti Márẹ́ṣà sọ àsọtẹ́lẹ̀ sí Jèhóṣáfátì, ó ní: “Torí pé o bá Ahasáyà da nǹkan pọ̀, Jèhófà yóò pa iṣẹ́ rẹ run.”+ Nítorí náà, àwọn ọkọ̀ òkun náà fọ́,+ wọn kò sì lè lọ sí Táṣíṣì.
-