2 Àwọn Ọba 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Nígbà náà, Ahasáyà já bọ́ láti ibi asẹ́ tó wà ní yàrá òrùlé rẹ̀ ní Samáríà, ó sì fara pa. Torí náà, ó rán àwọn òjíṣẹ́, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ wádìí lọ́dọ̀ Baali-sébúbù ọlọ́run Ẹ́kírónì+ bóyá ibi tí mo fi ṣèṣe yìí máa san.”+
2 Nígbà náà, Ahasáyà já bọ́ láti ibi asẹ́ tó wà ní yàrá òrùlé rẹ̀ ní Samáríà, ó sì fara pa. Torí náà, ó rán àwọn òjíṣẹ́, ó sì sọ fún wọn pé: “Ẹ lọ wádìí lọ́dọ̀ Baali-sébúbù ọlọ́run Ẹ́kírónì+ bóyá ibi tí mo fi ṣèṣe yìí máa san.”+