-
1 Sámúẹ́lì 2:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Nígbà náà, màá yan àlùfáà olóòótọ́ kan fún ara mi.+ Ohun tí ọkàn mi bá fẹ́ ni á sì máa ṣe; màá kọ́ ilé kan tó máa wà pẹ́ títí fún un, á sì máa sìn níwájú ẹni àmì òróró mi nígbà gbogbo.
-
-
1 Kíróníkà 6:53Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
53 ọmọ rẹ̀ ni Sádókù,+ ọmọ rẹ̀ ni Áhímáásì.
-
-
1 Kíróníkà 12:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 àti Sádókù,+ ọ̀dọ́kùnrin kan tó lágbára, tó sì nígboyà pẹ̀lú àwọn olórí méjìlélógún (22) láti agbo ilé bàbá rẹ̀.
-
-
1 Kíróníkà 24:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Dáfídì àti Sádókù+ látinú àwọn ọmọ Élíásárì àti Áhímélékì látinú àwọn ọmọ Ítámárì pín wọn sí àwùjọ-àwùjọ gẹ́gẹ́ bí iṣẹ́ ìsìn wọn.
-