1 Àwọn Ọba 2:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Nítorí náà, Sólómọ́nì lé Ábíátárì kúrò lẹ́nu ṣíṣe àlùfáà fún Jèhófà, láti mú ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ sí ilé Élì+ ní Ṣílò+ ṣẹ. 1 Àwọn Ọba 2:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Lẹ́yìn náà, ọba yan Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà ṣe olórí ọmọ ogun ní ipò rẹ̀, ọba tún yan àlùfáà Sádókù+ sí ipò Ábíátárì. 1 Kíróníkà 29:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Wọ́n ń jẹ, wọ́n sì ń mu níwájú Jèhófà ní ọjọ́ yẹn tìdùnnútìdùnnú,+ wọ́n fi Sólómọ́nì ọmọ Dáfídì jẹ ọba lẹ́ẹ̀kejì, wọ́n sì fòróró yàn án níwájú Jèhófà láti jẹ́ aṣáájú,+ bákan náà wọ́n yan Sádókù láti jẹ́ àlùfáà.+
27 Nítorí náà, Sólómọ́nì lé Ábíátárì kúrò lẹ́nu ṣíṣe àlùfáà fún Jèhófà, láti mú ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ sí ilé Élì+ ní Ṣílò+ ṣẹ.
35 Lẹ́yìn náà, ọba yan Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà ṣe olórí ọmọ ogun ní ipò rẹ̀, ọba tún yan àlùfáà Sádókù+ sí ipò Ábíátárì.
22 Wọ́n ń jẹ, wọ́n sì ń mu níwájú Jèhófà ní ọjọ́ yẹn tìdùnnútìdùnnú,+ wọ́n fi Sólómọ́nì ọmọ Dáfídì jẹ ọba lẹ́ẹ̀kejì, wọ́n sì fòróró yàn án níwájú Jèhófà láti jẹ́ aṣáájú,+ bákan náà wọ́n yan Sádókù láti jẹ́ àlùfáà.+