-
1 Àwọn Ọba 22:51Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
51 Ahasáyà+ ọmọ Áhábù di ọba lórí Ísírẹ́lì ní Samáríà lọ́dún kẹtàdínlógún Jèhóṣáfátì ọba Júdà, ó sì fi ọdún méjì ṣàkóso lórí Ísírẹ́lì.
-