-
1 Àwọn Ọba 17:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Obìnrin náà wá sọ fún Èlíjà pé: “Mo ti wá mọ̀ báyìí pé èèyàn Ọlọ́run+ ni ọ́ lóòótọ́ àti pé ọ̀rọ̀ Jèhófà tó wà lẹ́nu rẹ jẹ́ òótọ́.”
-