-
2 Kíróníkà 22:3, 4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Òun náà ṣe ohun tí àwọn ará ilé Áhábù ṣe,+ nítorí ìyá rẹ̀ ni agbani-nímọ̀ràn rẹ̀ tó ń gbà á nímọ̀ràn láti máa hùwà burúkú. 4 Ó ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà nìṣó, bí ilé Áhábù ti ṣe, nítorí àwọn ni agbani-nímọ̀ràn rẹ̀ lẹ́yìn tí bàbá rẹ̀ kú, ìyẹn ló sì fa ìparun rẹ̀.
-