1 Àwọn Ọba 19:16, 17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kí o fòróró yan Jéhù+ ọmọ ọmọ Nímúṣì ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì, kí o sì yan Èlíṣà* ọmọ Ṣáfátì láti Ebẹli-méhólà ṣe wòlíì ní ipò rẹ.+ 17 Ẹni tó bá bọ́ lọ́wọ́ idà Hásáẹ́lì,+ Jéhù yóò pa á;+ ẹni tó bá sì bọ́ lọ́wọ́ idà Jéhù, Èlíṣà yóò pa á.+
16 Kí o fòróró yan Jéhù+ ọmọ ọmọ Nímúṣì ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì, kí o sì yan Èlíṣà* ọmọ Ṣáfátì láti Ebẹli-méhólà ṣe wòlíì ní ipò rẹ.+ 17 Ẹni tó bá bọ́ lọ́wọ́ idà Hásáẹ́lì,+ Jéhù yóò pa á;+ ẹni tó bá sì bọ́ lọ́wọ́ idà Jéhù, Èlíṣà yóò pa á.+