-
2 Kíróníkà 24:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Nígbàkigbà tí àwọn ọmọ Léfì bá gbé àpótí náà wá kí wọ́n lè kó ohun tó wà nínú rẹ̀ fún ọba, tí wọ́n sì rí i pé owó ti pọ̀ nínú rẹ̀, akọ̀wé ọba àti kọmíṣọ́nnà tó ń ṣojú olórí àlùfáà á wá, wọ́n á kó ohun tó wà nínú àpótí+ náà, wọ́n á sì dá a pa dà sí àyè rẹ̀. Ohun tí wọ́n máa ń ṣe nìyẹn lójoojúmọ́, wọ́n sì rí ọ̀pọ̀ owó kó jọ.
-