2 Àwọn Ọba 12:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nígbàkigbà tí wọ́n bá rí i pé owó ti pọ̀ nínú àpótí náà, akọ̀wé ọba àti àlùfáà àgbà á wá, wọ́n á kó owó náà,* wọ́n á sì ka owó tí àwọn èèyàn mú wá sí ilé Jèhófà.+
10 Nígbàkigbà tí wọ́n bá rí i pé owó ti pọ̀ nínú àpótí náà, akọ̀wé ọba àti àlùfáà àgbà á wá, wọ́n á kó owó náà,* wọ́n á sì ka owó tí àwọn èèyàn mú wá sí ilé Jèhófà.+