2 Àwọn Ọba 14:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ó pa àwọn ọmọ Édómù+ ní Àfonífojì Iyọ̀,+ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) èèyàn ló kú, ó sì gba ìlú Sẹ́ẹ́là lójú ogun,+ orúkọ ìlú náà sì di Jókítéélì títí di òní yìí.
7 Ó pa àwọn ọmọ Édómù+ ní Àfonífojì Iyọ̀,+ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) èèyàn ló kú, ó sì gba ìlú Sẹ́ẹ́là lójú ogun,+ orúkọ ìlú náà sì di Jókítéélì títí di òní yìí.