7 Àmì tí Jèhófà fún ọ nìyí láti mú un dá ọ lójú pé Jèhófà máa mú ọ̀rọ̀ tó sọ ṣẹ:+ 8 Màá mú kí òjìji oòrùn tó ń sọ̀ kalẹ̀ lórí àtẹ̀gùn Áhásì pa dà sẹ́yìn ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá.”’”+ Oòrùn wá pa dà sẹ́yìn ní ìgbésẹ̀ mẹ́wàá lẹ́yìn tó ti kọ́kọ́ lọ síwájú lórí àtẹ̀gùn náà.