-
Àìsáyà 39:5-7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àìsáyà wá sọ fún Hẹsikáyà pé: “Gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, 6 ‘Wò ó! Ọjọ́ ń bọ̀ tí wọ́n máa kó gbogbo ohun tó wà nínú ilé* rẹ àti gbogbo ohun tí àwọn baba ńlá rẹ ti kó jọ títí di òní yìí lọ sí Bábílónì. Kò ní ku nǹkan kan,’+ ni Jèhófà wí.+ 7 ‘Wọ́n á mú àwọn kan lára àwọn ọmọ tí o máa bí, wọ́n á sì di òṣìṣẹ́ ààfin ní ààfin ọba Bábílónì.’”+
-