2 Kíróníkà 34:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nígbà tí wọ́n ń kó owó táwọn èèyàn mú wá sí ilé Jèhófà jáde,+ àlùfáà Hilikáyà rí ìwé Òfin+ tí Jèhófà fún wọn nípasẹ̀* Mósè.+ 15 Torí náà, Hilikáyà sọ fún Ṣáfánì akọ̀wé pé: “Mo ti rí ìwé Òfin ní ilé Jèhófà.” Ni Hilikáyà bá fún Ṣáfánì ní ìwé náà.
14 Nígbà tí wọ́n ń kó owó táwọn èèyàn mú wá sí ilé Jèhófà jáde,+ àlùfáà Hilikáyà rí ìwé Òfin+ tí Jèhófà fún wọn nípasẹ̀* Mósè.+ 15 Torí náà, Hilikáyà sọ fún Ṣáfánì akọ̀wé pé: “Mo ti rí ìwé Òfin ní ilé Jèhófà.” Ni Hilikáyà bá fún Ṣáfánì ní ìwé náà.