1 Àwọn Ọba 2:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Lẹ́yìn náà, ọba yan Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà ṣe olórí ọmọ ogun ní ipò rẹ̀, ọba tún yan àlùfáà Sádókù+ sí ipò Ábíátárì.
35 Lẹ́yìn náà, ọba yan Bẹnáyà+ ọmọ Jèhóádà ṣe olórí ọmọ ogun ní ipò rẹ̀, ọba tún yan àlùfáà Sádókù+ sí ipò Ábíátárì.