Jẹ́nẹ́sísì 10:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ọmọ Gómérì ni Áṣíkénásì,+ Rífátì àti Tógámà.+ Ìsíkíẹ́lì 27:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ilé Tógámà+ fi ẹṣin àti àwọn ẹṣin ogun àti àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́* ṣe pàṣípààrọ̀ ọjà lọ́dọ̀ rẹ.