-
2 Sámúẹ́lì 6:9-11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Torí náà, ẹ̀rù Jèhófà+ ba Dáfídì ní ọjọ́ yẹn, ó sì sọ pé: “Kí ló dé tí a ó fi gbé Àpótí Jèhófà wá sọ́dọ̀ mi?”+ 10 Dáfídì kò fẹ́ gbé Àpótí Jèhófà wá sọ́dọ̀ ara rẹ̀ ní Ìlú Dáfídì.+ Kàkà bẹ́ẹ̀, Dáfídì ní kí wọ́n gbé e lọ sí ilé Obedi-édómù+ ará Gátì.
11 Oṣù mẹ́ta ni Àpótí Jèhófà fi wà ní ilé Obedi-édómù ará Gátì, Jèhófà sì ń bù kún Obedi-édómù àti gbogbo agbo ilé rẹ̀.+
-