1 Sámúẹ́lì 6:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Torí náà, àwọn èèyàn Bẹti-ṣémẹ́ṣì béèrè pé: “Ta ló lè dúró níwájú Jèhófà Ọlọ́run mímọ́ yìí,+ ọ̀dọ̀ ta ló sì máa lọ tí á fi kúrò lọ́dọ̀ wa?”+ Sáàmù 119:120 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 120 Ẹ̀rù rẹ mú kí ara* mi máa gbọ̀n;Mò ń bẹ̀rù àwọn ìdájọ́ rẹ.
20 Torí náà, àwọn èèyàn Bẹti-ṣémẹ́ṣì béèrè pé: “Ta ló lè dúró níwájú Jèhófà Ọlọ́run mímọ́ yìí,+ ọ̀dọ̀ ta ló sì máa lọ tí á fi kúrò lọ́dọ̀ wa?”+