ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Sámúẹ́lì 10:17-19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Nígbà tí wọ́n ròyìn fún Dáfídì, lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó kó gbogbo Ísírẹ́lì jọ, ó sọdá Jọ́dánì, ó sì wá sí Hélámù. Ìgbà náà ni àwọn ará Síríà to ara wọn lọ́wọ̀ọ̀wọ́ láti pàdé Dáfídì, wọ́n sì bá a jà.+ 18 Àmọ́, àwọn ará Síríà sá kúrò níwájú Ísírẹ́lì; Dáfídì sì pa ọgọ́rùn-ún méje (700) àwọn tó ń gun kẹ̀kẹ́ ẹṣin àti ọ̀kẹ́ méjì (40,000) àwọn agẹṣin ará Síríà, ó ṣá Ṣóbákì olórí àwọn ọmọ ogun wọn balẹ̀, ó sì kú síbẹ̀.+ 19 Nígbà tí gbogbo àwọn ọba àti àwọn ìránṣẹ́ Hadadésà rí i pé Ísírẹ́lì ti ṣẹ́gun àwọn, wọ́n tètè wá àlàáfíà lọ́dọ̀ Ísírẹ́lì, wọ́n sì di ọmọ abẹ́ wọn;+ ẹ̀rù wá ń ba àwọn ará Síríà láti tún ran àwọn ọmọ Ámónì lọ́wọ́.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́