-
1 Kíróníkà 11:23, 24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ó tún mú ọkùnrin ará Íjíbítì kan tó tóbi fàkìàfakia balẹ̀ tó ga ní ìgbọ̀nwọ́ márùn-ún.*+ Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ọ̀kọ̀ tó wà ní ọwọ́ ará Íjíbítì náà dà bí ọ̀pá àwọn ahunṣọ,*+ ó fi ọ̀pá bá a jà, ó já ọ̀kọ̀ náà gbà ní ọwọ́ ará Íjíbítì náà, ó sì fi ọ̀kọ̀ òun fúnra rẹ̀ pa á.+ 24 Àwọn ohun tí Bẹnáyà ọmọ Jèhóádà ṣe nìyẹn, ó lórúkọ bí àwọn akíkanjú jagunjagun mẹ́ta náà.
-