2 Àwọn Ọba 11:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àwọn olórí ọgọ́rọ̀ọ̀rún+ ṣe ohun tí àlùfáà Jèhóádà pa láṣẹ fún wọn gẹ́lẹ́. Torí náà, kálukú mú àwọn ọkùnrin rẹ̀ tó wà lẹ́nu iṣẹ́ ní Sábáàtì pẹ̀lú àwọn tí kò sí lẹ́nu iṣẹ́ ní Sábáàtì, wọ́n sì wá sọ́dọ̀ àlùfáà Jèhóádà.+ Lúùkù 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Bó ṣe ń ṣiṣẹ́ àlùfáà nínú iṣẹ́ tí a yàn fún ìpín rẹ̀+ níwájú Ọlọ́run, Lúùkù 1:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nígbà tí àwọn ọjọ́ tó fi ń ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́* pé, ó lọ sílé rẹ̀.
9 Àwọn olórí ọgọ́rọ̀ọ̀rún+ ṣe ohun tí àlùfáà Jèhóádà pa láṣẹ fún wọn gẹ́lẹ́. Torí náà, kálukú mú àwọn ọkùnrin rẹ̀ tó wà lẹ́nu iṣẹ́ ní Sábáàtì pẹ̀lú àwọn tí kò sí lẹ́nu iṣẹ́ ní Sábáàtì, wọ́n sì wá sọ́dọ̀ àlùfáà Jèhóádà.+