ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 16:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Ṣùgbọ́n Jèhófà sọ fún Sámúẹ́lì pé: “Má wo ìrísí rẹ̀ àti bí ó ṣe ga tó,+ torí pé mo ti kọ̀ ọ́. Nítorí ọ̀nà tí èèyàn gbà ń wo nǹkan kọ́ ni Ọlọ́run gbà ń wo nǹkan, torí pé ohun tí ó bá hàn síta ni èèyàn ń rí, ṣùgbọ́n Jèhófà ń rí ohun tó wà nínú ọkàn.”+

  • 1 Kíróníkà 29:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ọlọ́run mi, mo mọ̀ dáadáa pé o máa ń ṣàyẹ̀wò ọkàn+ àti pé o fẹ́ràn ìwà títọ́.*+ Nínú òótọ́* ọkàn ni mo fínnú-fíndọ̀ pèsè gbogbo nǹkan yìí, ayọ̀ mi sì kún láti rí àwọn èèyàn rẹ tó wá síbí láti ṣe ọrẹ àtinúwá fún ọ.

  • Òwe 17:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ìkòkò tí wọ́n fi ń yọ́ nǹkan mọ́ wà fún fàdákà, iná ìléru sì wà fún wúrà,+

      Àmọ́ Jèhófà ni olùṣàyẹ̀wò ọkàn.+

  • Ìfihàn 2:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Màá fi àjàkálẹ̀ àrùn pa àwọn ọmọ rẹ̀, kí gbogbo ìjọ lè mọ̀ pé èmi ni ẹni tó ń wá èrò inú* àti ọkàn, màá sì san án fún ẹnì kọ̀ọ̀kan yín bí iṣẹ́ yín bá ṣe rí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́