Nehemáyà 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àwọn ọmọ Hásénà mọ Ẹnubodè Ẹja;+ wọ́n fi ẹ̀là gẹdú kọ́ ọ,+ lẹ́yìn náà, wọ́n gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ sí i àti àwọn ìkọ́ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀.
3 Àwọn ọmọ Hásénà mọ Ẹnubodè Ẹja;+ wọ́n fi ẹ̀là gẹdú kọ́ ọ,+ lẹ́yìn náà, wọ́n gbé àwọn ilẹ̀kùn rẹ̀ sí i àti àwọn ìkọ́ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀.