2 Kíróníkà 33:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Ọmọ ọdún méjìlá (12) ni Mánásè+ nígbà tó jọba, ọdún márùndínlọ́gọ́ta (55) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ 2 Kíróníkà 33:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lẹ́yìn náà, ó mọ ògiri ẹ̀yìn òde sí Ìlú Dáfídì+ lápá ìwọ̀ oòrùn Gíhónì+ ní àfonífojì títí dé Ẹnubodè Ẹja,+ ó mọ ọ́n yí ká dé Ófélì,+ ó sì mú kí ó ga gan-an. Yàtọ̀ síyẹn, ó yan àwọn olórí ọmọ ogun sí gbogbo àwọn ìlú olódi ní Júdà. Sefanáyà 1:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ní ọjọ́ yẹn,” ni Jèhófà wí,“Igbe ẹkún máa wá láti Ẹnubodè Ẹja+Àti ìpohùnréré ẹkún láti Apá Kejì ìlú náà+Àti ìfọ́yángá láti àwọn òkè.
33 Ọmọ ọdún méjìlá (12) ni Mánásè+ nígbà tó jọba, ọdún márùndínlọ́gọ́ta (55) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+
14 Lẹ́yìn náà, ó mọ ògiri ẹ̀yìn òde sí Ìlú Dáfídì+ lápá ìwọ̀ oòrùn Gíhónì+ ní àfonífojì títí dé Ẹnubodè Ẹja,+ ó mọ ọ́n yí ká dé Ófélì,+ ó sì mú kí ó ga gan-an. Yàtọ̀ síyẹn, ó yan àwọn olórí ọmọ ogun sí gbogbo àwọn ìlú olódi ní Júdà.
10 Ní ọjọ́ yẹn,” ni Jèhófà wí,“Igbe ẹkún máa wá láti Ẹnubodè Ẹja+Àti ìpohùnréré ẹkún láti Apá Kejì ìlú náà+Àti ìfọ́yángá láti àwọn òkè.