ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 13:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ó kéde sórí pẹpẹ náà bí Jèhófà ṣe pàṣẹ fún un, ó ní: “Ìwọ pẹpẹ, pẹpẹ! Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Wò ó! Wọ́n á bí ọmọkùnrin kan tó ń jẹ́ Jòsáyà+ ní ilé Dáfídì! Ó máa fi àwọn àlùfáà ibi gíga rúbọ lórí rẹ, ìyẹn àwọn tó ń mú ẹbọ rú èéfín lórí rẹ, ó sì máa sun egungun èèyàn lórí rẹ.’”+

  • Sefanáyà 1:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 1 Ọ̀rọ̀ Jèhófà sí Sefanáyà* ọmọ Kúúṣì, ọmọ Gẹdaláyà, ọmọ Amaráyà, ọmọ Hẹsikáyà nígbà ayé Jòsáyà+ ọmọ Ámọ́nì+ ọba Júdà:

  • Mátíù 1:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Hẹsikáyà bí Mánásè;+

      Mánásè bí Ámọ́nì;+

      Ámọ́nì bí Jòsáyà;+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́