1 Àwọn Ọba 21:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 “Ṣé o rí bí Áhábù ṣe rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ nítorí mi?+ Torí pé ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ níwájú mi, mi ò ní mú àjálù náà wá nígbà ayé rẹ̀. Ìgbà ayé ọmọ rẹ̀ ni màá mú àjálù náà wá sórí ilé rẹ̀.”+ Àìsáyà 39:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ni Hẹsikáyà bá sọ fún Àìsáyà pé: “Ọ̀rọ̀ Jèhófà tí o sọ dáa.” Ó wá fi kún un pé: “Torí àlàáfíà àti ìfọkànbalẹ̀* máa wà lásìkò* tèmi.”+
29 “Ṣé o rí bí Áhábù ṣe rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ nítorí mi?+ Torí pé ó rẹ ara rẹ̀ sílẹ̀ níwájú mi, mi ò ní mú àjálù náà wá nígbà ayé rẹ̀. Ìgbà ayé ọmọ rẹ̀ ni màá mú àjálù náà wá sórí ilé rẹ̀.”+
8 Ni Hẹsikáyà bá sọ fún Àìsáyà pé: “Ọ̀rọ̀ Jèhófà tí o sọ dáa.” Ó wá fi kún un pé: “Torí àlàáfíà àti ìfọkànbalẹ̀* máa wà lásìkò* tèmi.”+