-
2 Àwọn Ọba 23:22, 23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Kò sí Ìrékọjá tí wọ́n ṣe tó dà bí èyí láti ìgbà tí àwọn onídàájọ́ ti ń ṣe ìdájọ́ Ísírẹ́lì tàbí ní gbogbo ìgbà tí àwọn ọba Ísírẹ́lì àti àwọn ọba Júdà ti ń jọba.+ 23 Àmọ́ ní ọdún kejìdínlógún Ọba Jòsáyà, wọ́n ṣe Ìrékọjá yìí fún Jèhófà ní Jerúsálẹ́mù.
-
-
2 Kíróníkà 30:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Ìdùnnú ṣubú layọ̀ ní Jerúsálẹ́mù, torí pé láti ìgbà ayé Sólómọ́nì ọmọ Dáfídì ọba Ísírẹ́lì, irú èyí ò ṣẹlẹ̀ ní Jerúsálẹ́mù.+
-