-
1 Kíróníkà 29:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Jèhófà sọ Sólómọ́nì di ẹni ńlá tó ta yọ lójú gbogbo Ísírẹ́lì, ó sì fi iyì ọba dá a lọ́lá débi pé kò sí ọba kankan ní Ísírẹ́lì tó nírú iyì bẹ́ẹ̀ rí.+
-
-
2 Kíróníkà 9:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Nítorí náà, ọrọ̀ àti ọgbọ́n Ọba Sólómọ́nì pọ̀ ju ti gbogbo àwọn ọba yòókù láyé.+
-
-
Oníwàásù 2:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Torí náà, mo dẹni ńlá, mo sì ga ju gbogbo àwọn tó wà ṣáájú mi ní Jerúsálẹ́mù.+ Bẹ́ẹ̀ ni ọgbọ́n mi kò fi mí sílẹ̀.
-