1 Àwọn Ọba 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Yàtọ̀ síyẹn, màá fún ọ ní ohun tí o kò béèrè,+ àti ọrọ̀ àti ògo,+ tó fi jẹ́ pé kò ní sí ọba míì tó máa dà bí rẹ ní gbogbo ọjọ́ ayé* rẹ.+ 1 Àwọn Ọba 10:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Nítorí náà, ọrọ̀+ àti ọgbọ́n+ Ọba Sólómọ́nì pọ̀ ju ti gbogbo àwọn ọba yòókù láyé.
13 Yàtọ̀ síyẹn, màá fún ọ ní ohun tí o kò béèrè,+ àti ọrọ̀ àti ògo,+ tó fi jẹ́ pé kò ní sí ọba míì tó máa dà bí rẹ ní gbogbo ọjọ́ ayé* rẹ.+