-
Sáàmù 22:27Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
27 Gbogbo ayé á rántí, wọ́n á sì yíjú sọ́dọ̀ Jèhófà.
Gbogbo ìdílé àwọn orílẹ̀-èdè á tẹrí ba níwájú rẹ.+
-
-
Sáàmù 46:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 “Ẹ túúbá, kí ẹ sì mọ̀ pé èmi ni Ọlọ́run.
-