1 Àwọn Ọba 1:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Àlùfáà Sádókù àti wòlíì Nátánì yóò fòróró yàn án+ níbẹ̀ ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì; lẹ́yìn náà kí ẹ fun ìwo, kí ẹ sì sọ pé, ‘Kí ẹ̀mí Ọba Sólómọ́nì gùn o!’+ Sáàmù 18:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìgbàlà* ńlá fún ọba rẹ̀;+Ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹni àmì òróró rẹ̀,+Sí Dáfídì àti àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ títí láé.+
34 Àlùfáà Sádókù àti wòlíì Nátánì yóò fòróró yàn án+ níbẹ̀ ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì; lẹ́yìn náà kí ẹ fun ìwo, kí ẹ sì sọ pé, ‘Kí ẹ̀mí Ọba Sólómọ́nì gùn o!’+
50 Ó ń ṣe àwọn iṣẹ́ ìgbàlà* ńlá fún ọba rẹ̀;+Ó ní ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ sí ẹni àmì òróró rẹ̀,+Sí Dáfídì àti àtọmọdọ́mọ* rẹ̀ títí láé.+